KÀYÉÉFÌ, ỌKÙNRIN KAN LU ỌMỌ OṢÙ MÉJÌ PA N'ILU ÒṢOGBO. Ọwọ́ àwọn agbófinró ti tẹ arákùnrin ẹni ọdún mẹ́tàlélógójì(43) kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sanjọ́ n'ilu Òṣogbo. Ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn arákùnrin ọ̀ún ni wípé ó lu ọmọ bíbí inú rẹ̀ ọmọ oṣù méjì lálùpa lágbègbè Alékúnwodò, Òṣogbo. Ará...